AWON AYE LO SO BEE…..
By OTUNBA TIFASE
A’gbo s’aasi nan-han L’agi Aya Arede….,
Tigi-tope lii Gbon’wu Egigun l’oko…..,
T’omode t’agba lii fe ti Ewe Oliyemiye….,
Bi Ina ba jo loko, manjala nii royin hi F’ara ile…,
Ero Okun, Ero osa, oya e wa f’enun Iyo wi ti OMO EKUN ( SENATOR ADENIYI ADEGBONMIRE)…., ENUN IYO…..,
Nitori Alara fenun Iyo wi T’ara…, ENUN IYO….,
Ajero fenun Iyo wi T’ijero…., ENUN IYO……,
Iran APASA a f’enun Iyo wi T’aso…, ENUN IYO…..,
Iran OBIRI f’enun Iyo wi T’akese ooo…, ENUN IYOOOOOOO….,
#OMO EKUN ( SENATOR ADENIYI ADEGBONMIRE D’ERU JEJE…….#
#EKUN OKO IYA WON DEE……#
#ONDO CENTRAL SENATORIAL DISTRICT ….#
#OMO EKUN NI OOOO….#
Itesiwaju ondo central ni ADEGBONMIRE
By : OTUNBA TIFASE
‘CEO’ CARDINAL POINT CONSULTANCY INFORMATION & COMMUNICATION FIRM.

